Ata
Ìrísí
Ata ni ohun èso tí a ká tí a sì fi pèsè yálà ohun jíjẹ bí Ọbẹ̀ tàbí mímu mìíràn kí ó le ta lẹ́nu kí ó sì lè ṣe ànfàní fún ará. Pàá pàá jùlọ lásìkò òtútù tàbí ọ̀gìnìntìn. [1][2]

Ata leè tọ́ka sí :
Oríṣi ata fún oúnjẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ata rodo
- Ata ṣọ̀mbọ̀
- Ata gbígbẹ
- Ata ilẹ̀
- Ata Tàtàṣé
- Tìmọ́ọ̀tì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [3][4]
Sì ẹgbẹ́ olórin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper (band), ẹgbẹ́ olórin kan tí wọ́n ń kó orin rock-reggae láti Hawaii
- The Peppers, ẹgbẹ́ ọmọ olórin ilẹ̀ faransé
- "Pepper" (orin), tí ọdún 1996, láti ọwọ́o Butthole Surfers
- "Pepper", Orin ohun èlò orin láti owóo (song by Linkin Park) LP Underground 11
- "Pepper", orin kan láti owóo Death Cab fun Cutie láti inú àwo orin rẹ tí ọdún 2022 Asphalt Meadows
- "Peppers", orin kan láti owóo Lana Del Rey nínú àwọ Orin rè Did You Know That There's a Tunnel Under Ocean Blvd tí ọdún 2023
- Sgt. Pepper's Lonely Hearts Club Band tí ó jẹ́ àgbélèroẹ̀dá-ìtàn pàtàkì àwọn ẹgbẹ́ olorin The Beatles.
Àwọn ènìyàn àgbélèro nínú eré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper (name), Àtòjọ àwọn ènìyàn tí wọ́n jẹ́ àgbélèro pẹ̀lú orúkọ, yálà àbíso, orúkọ ìnagijẹ tàbí tí ìdílé.
- Peppers (surname), Àtòjọ àwọn ènìyàn tí orúkọ ìdílé wọn jẹ pepper.
- Pepper Gomez, orúkọ eré oníjà àti eléré agbérin ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan José Gomez (1927–2004)
- Pepper Martin (actor), orúkọ eré oníjàkadì kan ọmọ orílẹ̀ èdè Canadian-American ti o tún jẹ́ òṣèré orí ìtàgé, Howard Martin (1936–2022)
- Pepper Parks, orúkọ eré oníjàkadì ọmọ Amẹ́ríkà kan, Jesse Guilmette (born 1980), tí ìnagije rẹ ń tún jẹ́ "The Blade"
- Pepper, orúkọ eré ẹ Cynthia Peretti (1948–2009), tí ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan tí ó jẹ́ onìjàkadì.
Àwọn agbègbè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper, West Virginia, agbègbè kan ní US.
- Pepper Creek (Delaware), orúkọ odò kan ní US.
- Pepper Creek, Marion Township, Davis County, Iowa, Odò kan ní US.
- Cockspur Island, ni agbègbè Georgia, ní US, tí a mọ̀ sí Pepper Island tẹ̀lé.
- Langkawi, ní Malaysia, tí àwọn ọmọ ológun orí omi ilè British mò gẹ́gẹ́bi Pepper Island.
Ìmò ìjìnlè àti Ìtèsíwájú ìmọ̀ ẹ̀rọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper (cryptography), Ìyípadà kékeré kí wọ́n to yí sí àmì àṣírí (hashing)
- Pepper (robot), Róbọ́òtì tó jọ ènìyàn láti owóo Aldebaran Robotics àti SoftBank Mobile
- PPAPI tàbí Pepper Plugin API, tí ó jẹ́ Ojú-ìwòye ẹ̀rọ fún èrò tí a fi ń wo orí ayélujára.
Níbi eré ìdárayá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper (baseball), ó jẹ́ eré ìdárayá àti eré ìje.
- Pepper (volleyball), Ìfidánrawò
- Newark Peppers, ẹgbẹ́ eré ìje Federal League baseball láti ọdún 1913 sí 1915
Àwọn ìlò ibòmíràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pepper (film), eré fíìmù ẹlérin ilé Amẹrikà tí ọdún 1936.
- "Pepper" (The Brak Show), ìpèlé eré àgbéléwò tí ọdún 2002
- Pepper (card game), orúkọ mìíràn fún Irúfẹ́ eré kádì ènìyàn mẹ́rìn (bid euchre)
- Pepper (dog), ẹ̀yà ajá Dalmatian tí ikú rẹ ṣe okùnfà òfin ètò àbọ̀ àwọn ǹkan òsìn tí ọdún 1966 (U.S. Animal Welfare Act of 1966)
- Perets' tàbí Pepper, ìwé ìròyìn afi àwàdà-aşẹ́fẹ́-danilẹ́kọ̀ọ́ Ilè Ukrainian.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "pepper - meaning of pepper in Longman Dictionary of Contemporary English". LDOCE. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Reid, Robert (2020-01-15). "The world’s most prized pepper?". BBC. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2019-09-06). "The different types of peppers we have in Nigeria". Pulse Nigeria. Retrieved 2020-01-19.
- ↑ BM, Myers; Al., Et. "Effect of red pepper and black pepper on the stomach.". NCBI. Retrieved 2020-01-19.
Tún yẹ àwọn eléyi náà wò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Dr Pepper, Ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò
- Pepper II, eré fídíò ọdún 1980s láti owóo Exidy game by Exidy
- Peppercorn (disambiguation)
- Peper
- Àdàkọ:In title
|
|
This disambiguation page lists articles associated with the title Ata. If an internal link led you here, you may wish to change the link to point directly to the intended article. |