Jump to content

Bilo-bilo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pinaltok or Bilo-bilo
Bilo-bilo
Alternative namesbilu-bilo, pinaltok, binignit, paradusdos, pinindot, ginataang bilo-bilo, ginataang halo-halo, tambo-tambong
CourseDessert
Place of originPhilippines
Serving temperatureHot or cold
Main ingredientsSticky rice coconut milk, sugar, saba, taro, sweet potato, pearl sago, landang, pandan leaves
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Pinaltok tàbí Bilo-bilo jẹ́ ohun Ìpanu kan ni ilé Philippines I tí wọ́n ṣe látàrí Ìrẹsì tí wọ́n ti lọ̀ tí wọ́n fi omi die sí tí wọ́n ra á ródóródó, èyí tí wọn sí ṣe nínú omi àgbọn [1] àti Ṣúgà. Àwọn ohun bí Jackfruit, Ọ̀gẹ̀dẹ̀, Ọ̀dùnkún, Taro, Tàbìókà, Ṣágo tí ó wà ní kékeré àti ńlá ni wọn yóò fi sí. Ìlú Luzon Luzon ni Bilo-bilo ni wọn ti ń kọ́kọ́ ń jẹ ẹ́.[2] Orísìírísìí ọ̀nà ni wọn ń gbà sèsé èyí tó jẹ́ mọ àgbègbè tí èèyàn bá wà ní Fílípìni. Àwọn ọ̀nà mi a nílò Àgbọ̀n àti ẹran, nígbà tí àwọn mìíràn a máa fi Ewé Pandan sèsé. Ní gbígbóná ni ó dára láti jẹ ṣùgbọ́n àwọn mìíràn a máa ní sùúrù kí ó tutù tàbí kí wọ́n gbé e sínú èrò amóhuntutù kí ó ba lè tútù kí wọ́n tó jẹ́ ẹ́.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Fernando, Gilda Cordero-; Baldemor, Manuel D. (1992) (in en). Philippine food & life: Luzon. Anvil Pub.. p. 17. ISBN 9789712702327. https://books.google.com/books?id=afuBAAAAMAAJ. Retrieved January 10, 2019.
  2. ↑ "Luzon". Britannica. Retrieved April 22, 2019.